Iwure
teni lati enu CHIEF DR FRED OLAIFA SPIRITUAL HOME THE MOST POWERFUL SPIRITUAL HOUSE IN OGUN AND KOGI STATE. ifa kan lo so
bayi wipe aganran ni kifa koro awoko ni yungba ope karo ni tori bo odo
lai fara kan omi adifa fun akope eluju eyi ti won ni yo ko ope kankan
soso la ni odun ebo loni ko wa se kope ona ko jin ewa bani ba jebutu ire
gbogbo wa pata ni ao la ni ase eledunmare(ASE)
No comments:
Post a Comment